Download music: Kemi Ogunrinde – EMIMIMO (Holy Spirit)

“Kemi Ogunrinde” has finally released his highly anticipated new single titled “EMIMIMO” means Holy Spirit.

DOWNLOAD HERE

LYRICS:
verse: jise re nde Jesu
Gbe oruko re ga
Mu kife re kokun inu okan gbogbo eniyan
Nipa emimimo
Ileri re nope waran olutunu siwa
Awa duro gege bi tigbani
Kunwa femimimo
Chorus: Emimimo lole bawa see
Agbara wa odankan
Eran ara ole gbe wa debikankan
Sowa ji o ninu re
Ileri re nope
Waran olutunu siwa
Anduro anreti ileri re
Kun wa femimimo
Chorus:Emimimo lole bawa see
Agbara wa odankan
Eran ara ole gbe wa debikankan
Sowa ji o ninu re
Ileri re nope
Waran olutunu siwa
Anduro anreti ileri re
Kun wa femimimo
Verse: kogun esu folo
Kogun orun apadi jona
Kagbara emimi de
Kin mase wa ni ihoho ‘nu emi
Emimimo gbami lowo eran ara
Kisohun nu Ife re nikan
Kemi re satona mi
Okunkun ko jona Lona mi
Imole re kotan yimika
Ide ojo pipe ko ja larami
Emi ayo wonu okanmi
Aye ose gbe laisi oreofe re
Bridge:
Lead:Nigba temi nkulo
Resp:oluwa gbemiro
Lead: tani yo ha gbami lowo eran ara kiku yi
Resp: oluwa gbemiro
Lead:Gbata gbara emimi pin olorun mi
Resp:oluwa mumi duro
Lead:kin mase ku Nigba timo walaye
Resp: oluwa wa gbemiro
Chorus:Emimimo lole bawa see
Agbara wa odankan
Eran ara ole gbe wa debikankan
Sowa ji o ninu re
Ileri re nope
Waran olutunu siwa
Anduro anreti ileri re
Kun wa femimimo
Chorus:Emimimo lole bawa see
Agbara wa odankan
Eran ara ole gbe wa debikankan
Sowa ji o ninu re
Ileri re nope
Waran olutunu siwa
Anduro anreti ileri re
Kun wa femimimo
Bridge:
Lead: Emimimo gbewawo
Gbewawo kinmase fese ko ninu irinajo yi
Emimimo funmi ni ogbon latoke wa
kin le saseyori ninu irinajo yi olorun
Emimimo lati orun wa balemi oo

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Scroll to Top